Job 34:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni iṣẹju kan ni nwọn o kú, awọn enia a si di yiyọ lẹnu larin ọganjọ, nwọn a si kọja lọ; a si mu awọn alagbara kuro laifi ọwọ́ ṣe.

Job 34

Job 34:15-21