Job 26:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ṢUGBỌN Jobu si dahùn wipe,

2. Bawo ni iwọ nṣe iranlọwọ ẹniti kò ni ipá, bawo ni iwọ nṣe gbà apa ẹniti kò li agbara?

3. Bawo ni iwọ nṣe ìgbimọ ẹniti kò li ọgbọ́n, tabi bawo ni iwọ nsọdi ọ̀ran li ọ̀pọlọpọ bi o ti ri?

Job 26