Job 25:5-6 Yorùbá Bibeli (YCE)

5. Kiyesi i, òṣupa kò si le itan imọlẹ, ani awọn ìrawọ kò mọlẹ li oju rẹ̀.

6. Ambọtori enia ti iṣe idin, ati ọmọ enia, ti iṣe kòkoro!

Job 25