Job 19:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NIGBANA ni Jobu dahùn o si wipe,

2. Yio ti pẹ to ti ẹnyin o fi ma bà mi ninu jẹ, ti ẹnyin o fi ma fi ọ̀rọ kun mi ni ìjanja?

3. Igba mẹwa li ẹnyin ti ngàn mi, oju kò tì nyin ti ẹ fi jẹ mi niya.

Job 19