Job 17:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE) EMI mi bajẹ, ọjọ mi parun, isa-okú duro dè mi. Nitõtọ! awọn ẹlẹya wà lọdọ mi, oju mi si tẹmọ́