Job 14:20-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. Iwọ si ṣẹgun rẹ̀ lailai, on si kọja lọ iwọ pa awọ oju rẹ̀ dà, o si ran a lọ kuro.

21. Awọn ọmọ rẹ̀ bọ́ si ipo ọlá, on kò si mọ̀, nwọn si rẹ̀ silẹ, on kò si kiyesi i lara wọn.

22. Ṣugbọn ẹran-ara rẹ̀ ni yio ri irora, ọkàn rẹ̀ ni yio si ma ni ibinujẹ ninu rẹ̀.

Job 14