Joṣ 18:23-27 Yorùbá Bibeli (YCE) Ati Affimu, ati Para, ati Ofra; Ati Kefari-ammoni, ati Ofni, ati Geba; ilu mejila pẹlu ileto wọn: Gibeoni, ati Rama