Jer 48:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Fi iyẹ fun Moabu, ki o ba le fò ki o si lọ, ilu rẹ̀ yio si di ahoro, laisi ẹnikan lati gbe inu rẹ̀.

Jer 48

Jer 48:1-18