Jer 48:47 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sibẹ emi o tun mu igbekun Moabu pada li ọjọ ikẹhin, li Oluwa wi. Titi de ihin ni idajọ Moabu.

Jer 48

Jer 48:43-47