Jer 48:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi; Wò o, on o fò gẹgẹ bi idi, yio si nà iyẹ rẹ̀ lori Moabu.

Jer 48

Jer 48:38-47