Jer 34:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ijoye Juda, ati awọn ijoye Jerusalemu, awọn ìwẹfa, ati awọn alufa, ati gbogbo enia ilẹ na, ti o kọja lãrin ipin mejeji ẹgbọrọ malu na;

Jer 34

Jer 34:11-21