Jer 27:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi ti dá aiye, enia ati ẹranko ti o wà lori ilẹ aiye, nipa agbara nla mi, ati nipa ọwọ ninà mi, emi si fi i fun ẹnikẹni ti o wù mi.

Jer 27

Jer 27:1-11