Jer 23:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina sa wò o, emi dojukọ awọn woli, li Oluwa wi, ti o nji ọ̀rọ mi, ẹnikini lati ọwọ ẹnikeji rẹ̀.

Jer 23

Jer 23:20-33