Jer 18:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi orilẹ-ède na ti mo ti sọ ọ̀rọ si ba yipada kuro ninu ìwa-buburu rẹ̀, emi o yi ọkàn mi pada niti ibi ti emi ti rò lati ṣe si wọn.

Jer 18

Jer 18:2-15