Jer 15:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẽṣe ti irora mi pẹ́ titi, ati ọgbẹ mi jẹ alaiwotan, ti o kọ̀ lati jina? lõtọ iwọ si dabi kanga ẹ̀tan fun mi, bi omi ti kò duro?

Jer 15

Jer 15:15-21