Jer 13:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si lọ si odò Ferate, mo si walẹ̀, mo si mu àmure na jade kuro ni ibi ti emi ti fi i pamọ si, sa wò o, àmure na di hihù, kò si yẹ fun ohunkohun.

Jer 13

Jer 13:1-15