Jer 13:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni iwọ o sọ fun wọn pe, Bayi li Oluwa wi, sa wò o, emi o fi imutipara kún gbogbo olugbe ilẹ yi, ani awọn ọba ti o joko lori itẹ Dafidi, awọn alufa ati awọn woli, pẹlu gbogbo awọn olugbe Jerusalemu.

Jer 13

Jer 13:6-22