Jer 10:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li ẹnyin o wi fun wọn pe: Awọn ọlọrun ti kò da ọrun on aiye, awọn na ni yio ṣegbe loju aiye, ati labẹ ọrun wọnyi.

Jer 10

Jer 10:7-12