Isa 66:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, gbogbo ẹran-ara yio si wá tẹriba niwaju mi, lati oṣù titun de oṣù titun, ati lati ọjọ isimi de ọjọ isimi, li Oluwa wi.

Isa 66

Isa 66:16-24