Isa 57:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi kì yio jà titi lai, bẹ̃ni emi kì yio binu nigbagbogbo: nitori ẹmi iba daku niwaju mi, ati ẽmi ti emi ti dá.

Isa 57

Isa 57:8-21