Isa 56:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ wá, ni nwọn wi, emi o mu ọti-waini wá, a o si mu ọti-lile li amuyo; ọla yio si dabi ọjọ oni, yio si pọ̀ lọpọlọpọ.

Isa 56

Isa 56:5-12