Isa 5:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Oluwa awọn ọmọ-ogun li a o gbe ga ni idajọ, ati Ọlọrun Ẹni-Mimọ́ yio jẹ mimọ́ ninu ododo.

Isa 5

Isa 5:9-24