Isa 47:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni awọn ti iwọ ti ba ṣiṣẹ yio jẹ fun ọ, awọn oniṣowo rẹ, lati ewe rẹ wá; nwọn o kiri lọ, olukuluku si ẹkùn rẹ̀; ko si ẹnikan ti yio gbà ọ.

Isa 47

Isa 47:5-15