Isa 46:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti nsọ opin lati ipilẹṣẹ wá, ati nkan ti kò ti iṣe lati igbãni wá, wipe, Imọ mi yio duro, emi o si ṣe gbogbo ifẹ mi.

Isa 46

Isa 46:8-13