Isa 44:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori emi o dà omi lu ẹniti ongbẹ ngbẹ, ati iṣàn-omi si ilẹ gbigbẹ: emi o dà ẹmi mi si iru rẹ, ati ibukun mi si iru-ọmọ rẹ.

Isa 44

Isa 44:1-5