Isa 41:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori mo wò, kò si si ẹnikan; ani ninu wọn, kò si si olugbimọ̀ kan, nigbati mo bere lọwọ wọn, kò si ẹniti o le dahùn ọ̀rọ kan.

Isa 41

Isa 41:24-29