Isa 37:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tani iwọ kẹgàn ti o si sọ̀rọ buburu si? tani iwọ si gbe oju rẹ ga si, ti o si gbe oju rẹ soke gangan? si Ẹni-Mimọ́ Israeli ni.

Isa 37

Isa 37:17-25