Isa 32:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Titi a o fi tú Ẹmi jade si wa lara lati oke wá, ati ti aginju yio fi di ilẹ eléso, ti a o si kà ilẹ eleso si bi igbo.

Isa 32

Isa 32:10-20