Isa 30:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn akọ-malu pẹlu, ati awọn ọmọ kẹtẹkẹtẹ ti ntulẹ yio jẹ oko didùn, ti a ti fi kọ̀nkọsọ ati atẹ fẹ.

Isa 30

Isa 30:20-31