Isa 26:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa, ninu wahala ni nwọn wá ọ, nwọn gbadura wúyẹ́wúyẹ́ nigbati ibawi rẹ wà lara wọn.

Isa 26

Isa 26:11-21