Isa 24:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ilẹ pẹlu si di aimọ́ li abẹ awọn ti ngbe inu rẹ̀; nitori nwọn ti rú ofin, nwọn pa ilàna dà, nwọn dà majẹmu aiyeraiye.

Isa 24

Isa 24:3-8