Isa 17:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ na ni ilu alagbara rẹ̀ yio dabi ẹka ìkọsilẹ, ati ẹka tente oke ti nwọn fi silẹ nitori awọn ọmọ Israeli: iparun yio si wà.

Isa 17

Isa 17:1-14