Isa 10:29-31 Yorùbá Bibeli (YCE)

29. Nwọn ti rekọja ọ̀na na: nwọn ti wọ̀ ni Geba; Rama bẹ̀ru; Gibea ti Saulu sá.

30. Gbe ohùn rẹ soke, ọmọbinrin Gallimu: mu ki a gbọ́ ọ de Laiṣi, otòṣi Anatoti.

31. A ṣi Madmena nipo dà; awọn ara Gebimu ko ara wọn jọ lati sa.

Isa 10