2. Pet 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹ si mã kà a si pe, sũru Oluwa wa igbala ni; bi Paulu pẹlu, arakunrin wa olufẹ, ti kọwe si nyin, gẹgẹ bi ọgbọ́n ti a fifun u;

2. Pet 3

2. Pet 3:10-16