2. Kor 7:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ gbà wa tọkàntọkàn; a kò fi ibi ṣe ẹnikẹni, a kò bà ẹnikẹni jẹ, a kò rẹ́ ẹnikẹni jẹ.

2. Kor 7

2. Kor 7:1-7