2. Kor 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn gbogbo wa nwò ogo Oluwa laisi iboju bi ẹnipe ninu awojiji, a si npawada si aworan kanna lati ogo de ogo, ani bi lati ọdọ Oluwa ti iṣe Ẹmí.

2. Kor 3

2. Kor 3:10-18