2. A. Ọba 9:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wipe, Eke; sọ fun wa wayi. On si wipe, Bayi bayi li o sọ fun mi wipe, Bayi ni Oluwa wipe, Emi ti fi ororo yàn ọ li ọba lori Israeli.

2. A. Ọba 9

2. A. Ọba 9:7-22