2. A. Ọba 17:40-41 Yorùbá Bibeli (YCE)

40. Nwọn kò si gbọ́, ṣugbọn nwọn ṣe bi iṣe wọn atijọ.

41. Bẹ̃li awọn orilẹ-ède wọnyi bẹ̀ru Oluwa, ṣugbọn nwọn tun sin awọn ere fifin wọn pẹlu; awọn ọmọ wọn, ati awọn ọmọ-ọmọ wọn, bi awọn baba wọn ti ṣe, bẹ̃li awọn na nṣe titi fi di oni yi.

2. A. Ọba 17