Iṣe Apo 9:7-9 Yorùbá Bibeli (YCE)

7. Awọn ọkunrin ti nwọn si mba a re àjo duro, kẹ́kẹ pa mọ́ wọn li ẹnu, nwọn gbọ́ ohùn na, ṣugbọn nwọn kò ri ẹnikan.

8. Saulu si dide ni ilẹ; nigbati oju rẹ̀ si là kò ri ohunkan: ṣugbọn nwọn fà a li ọwọ́, nwọn si mu u wá si Damasku.

9. O si gbé ijọ mẹta li airiran, kò si jẹ, bẹ̃ni kò si mu.

Iṣe Apo 9