Iṣe Apo 7:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ni Mose na ti o wi fun awọn ọmọ Israeli pe, Woli kan li Oluwa Ọlọrun nyin yio gbé dide fun nyin ninu awọn arakunrin nyin, bi emi; on ni ki ẹ gbọ́ tirẹ.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:31-44