Iṣe Apo 5:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si tẹ̀ si tirẹ̀: nigbati nwọn si pè awọn aposteli wọle, nwọn lù wọn, nwọn si kìlọ fun wọn pe, ki nwọn ki o máṣe sọ̀rọ li orukọ Jesu mọ́, nwọn si jọwọ wọn lọwọ lọ.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:33-42