Iṣe Apo 27:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

O wipe, Má bẹ̀ru, Paulu; iwọ kò le ṣaima duro niwaju Kesari: si wo o, Ọlọrun ti fi gbogbo awọn ti o ba ọ wọkọ̀ pọ̀ fun ọ.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:19-26