Iṣe Apo 26:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ileri eyiti awọn ẹ̀ya wa mejejila ti nfi itara sin Ọlọrun lọsan ati loru ti nwọn nreti ati ri gba. Nitori ireti yi li awọn Ju ṣe nfi mi sùn, Agrippa Ọba.

Iṣe Apo 26

Iṣe Apo 26:6-17