Iṣe Apo 24:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awa ri ọkunrin yi, o jẹ onijagidi enia, ẹniti o ndá rukerudo silẹ lãrin gbogbo awọn Ju ti o wà ni gbogbo aiye, ati olori ẹ̀ya awọn Nasarene:

Iṣe Apo 24

Iṣe Apo 24:1-6