Iṣe Apo 13:51-52 Yorùbá Bibeli (YCE)

51. Ṣugbọn nwọn gbọ̀n ekuru ẹsẹ wọn si wọn, nwọn si wá si Ikonioni.

52. Awọn ọmọ-ẹhin si kún fun ayọ̀ ati fun Ẹmí Mimọ́.

Iṣe Apo 13