Iṣe Apo 13:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si mu u kuro, o gbé Dafidi dide li ọba fun wọn; ẹniti o si jẹri rẹ̀ pe, Mo ri Dafidi ọmọ Jesse ẹni bi ọkàn mi, ti yio ṣe gbogbo ifẹ mi.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:16-26