Iṣe Apo 10:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ni gbogbo orilẹ-ède, ẹniti o ba bẹ̀ru rẹ̀, ti o si nṣiṣẹ ododo, ẹni itẹwọgba ni lọdọ rẹ̀.

Iṣe Apo 10

Iṣe Apo 10:34-39