1. Sam 6:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ara Betṣemeṣi nkore alikama wọn li afonifoji: nwọn gbe oju wọn soke, nwọn si ri apoti na, nwọn si yọ̀ lati ri i.

1. Sam 6

1. Sam 6:7-17