1. Sam 30:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si ri ara Egipti kan li oko, nwọn si mu u tọ̀ Dafidi wá, nwọn si fun u li onjẹ, o si jẹ; nwọn si fun u li omi mu;

1. Sam 30

1. Sam 30:4-19