1. Sam 30:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ si bọ̀ si Siklagi ni ijọ kẹta, awọn ara Amaleki si ti kọlu iha ariwa, ati Siklagi, nwọn si ti kun u;

1. Sam 30

1. Sam 30:1-11